• globe
    • English
    • Беларуская мова
    • Български
    • Македонски
    • Монгол
    • Русский
    • Українська
    • тоҷикӣ
    • Қазақ тілі
    • Հայերեն
    • עברית
    • العربية
    • بَاسَا سُوْندَا
    • فارسی
    • کوردی
    • 中文 (简体)
    • नेपाली
    • मराठी
    • हिंदी
    • বাংলা
    • ਪੰਜਾਬੀ
    • 日本語
    • Čeština
    • ગુજરાતી
    • తెలుగు
    • ಕನ್ನಡ
    • 繁體中文
    • മലയാളം
    • සිංහල
    • ไทย
    • ພາສາລາວ
    • ကညီလံာ်ခီၣ်ထံး
    • ဗမာစာ
    • ဗမာစာ (Unicode)
    • ქართული
    • አማርኛ
    • 한국어
    • ខេមរភាសា
    • ‫اردو
    • ελληνικά
    • Afrikaans
    • Azərbaycanca
    • Bahasa Melayu
    • Bahasa Melayu Brunei
    • Cрпски
    • Català
    • Cymraeg
    • Dansk
    • Deutsch
    • Eesti
    • Español
    • Filipino
    • Français (Canada)
    • Français (France)
    • Hausa
    • Hmoob
    • Hrvatski
    • Ikirundi
    • Indonesia
    • isiXhosa
    • isiZulu
    • Italiano
    • Kiswahili
    • Kreyòl ayisyen
    • Latviašu
    • Lietuviškai
    • Luxembourgish
    • Magyar
    • Malagasy
    • Malti
    • Mooré
    • Nederlands
    • Norsk
    • Oʻzbek
    • Polski
    • Português
    • Română
    • Slovenčina
    • Slovenščina
    • Soomaaliga
    • Srpski
    • Suomi
    • Svenska
    • Türkçe
    • Tagalog
    • Tiếng Việt
    • Vlaams
    • Español (European Union)
    • Português (European Union)
    • English (UK)
    • íslenska
    • தமிழ்
    • Bosanski
    • gjuha shqipe
Client Login
Ethics Point - Integrity at Work

Ṣàkójọ Ìjábọ̀ Titun kan


 

Tọpinpin ìjábọ̀ tó wà tẹ́lẹ̀



Ńpèsè ìforúkọ́ pamọ́, ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ àṣírí fún àwọn ilé-iṣẹ́ káàkiri àgbáyé.

Ìlépa NAVEX Global ni láti ṣàrídájú pé o le sọ nípa àwọn ìṣòro àti ìrújú tó níṣe pẹ̀lú àwọn ìṣe tí kò bá òfin mu tabí tí kò dára lábẹ́ ààbò àti òtítọ́ pẹ̀lú ìṣàkóso ilé-iṣẹ́ tàbí ìgbìmọ̀ àwọn adarí tí o kò sì ní láti dárúkọ rẹ àti ààbò ohun àṣírí.

NAVEX Global jẹ́ Ibi Ààbò tí A Jẹ́rìísí nípasẹ̀ Ẹ̀ka Iṣẹ́ Ọrọ̀ Ajé ti United States bíi olùpèsè ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ tó ní ààbò láti dojúkọ ọgbọ́n-inú ìpamọ́ EU àti àwọn ìlànà ìpamọ́ àgbáyé míràn.

A tiraka láti jẹ́ kí jíjábọ̀ ìṣòro ati ìrújú nípasẹ̀ EthicsPoint™ rọrùn kó sì jẹ́ àìrújú. Àwọn ojúlé wẹ́ẹ̀bù wọ̀nyí yóò tọ́ọ sọ́nà nípa ìlànà náà nigbàtí a kò ní dárúkọ rẹ tàbí irú ẹni tí o jẹ́ ní ìgbésẹ̀ kọ̀ọ̀kan. Tẹ̀lé àwọn ìgbésẹ̀ wọ̀nyí láti fa ìjábọ̀ rẹ kalẹ̀:

  1. Tẹ orúkọ ilé-iṣẹ́ tí o ń fa ìjábọ̀ kalẹ̀ wọlé kí o sì yan àṣàyàn tó tọ̀nà
  2. Ṣíra tẹ Ìsọ̀rí Ìtàpásófin èyítí ó ṣàlàyé ìṣòro tí o ń jábọ̀ dáradára
  3. Faramọ́ "Àwọn Òfin àti Ìlànà" lẹ́yìn náà parí fọ́ọ̀mù náà
  4. Kí o tó fa ìjábọ̀ rẹ kalẹ̀, ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ aṣínà kan láti le tọpinpin ìjábọ̀ rẹ.

Lẹ́yìn tí o bá fa ìjábọ̀ rẹ kalẹ̀, a ó fún ọ ní kọ́kọ́rọ́ ìjábọ̀ kan. Ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ àti kọ́kọ́rọ́ ìjábọ̀ ń gbà ọ́ láàyè láti tọpinpin ìjábọ̀ rẹ.

NAVEX
Privacy Statement   |  Terms of Use   |  Cookie Statement     
© 2023 NAVEX Global Inc., All Rights Reserved.
TRUSTe
SAS70 Type II